You are here

Surulere!

Suuru jé oun Pataki ti gbogbo èniyan gbodo ni, aii ni Suuru si ti jè ki opolopo sè asisè  ti won ko si lè yii pada.Ninu oro owè,awon agba maa n so wipe”Ikanju ni isofo”.Eni ti o baa n kanju kii duro lati mo idi oro tabi otito idi oro rara, onikanju èniyan maa n yaara lati gba oun tii ko dani loju gbo, onikanju èniyan maa n sè asisè ti ko ni sii ona ati yii pada.Ninu oun gbogbo ti a baa n sè o ye kii a ko bii a tin ni SUURU ni gba Gbogbo.

A ko Nilo lati maa kanju sè idajo oro bii ko se kii a maa wa idi oro fini fini lati mo otito. Imi ninu owè awon agba tun maa n so wipè”oni suuru èyan lo nii oun Gbogbo”Onikanju èyan Kankan ko lè farabale se oun rèrè rara.Ai ni Suuru jè oun kan pato ti o ti gba okan awon èyan laye odè oni, paapa ju lo awon odo Kunrin ati obinrin.Gbogbo won ni won fe wa oko bogini,wo aso Asiko ati ojulowo pelu awon ero ati foonu gbajumo, Eso ara tii o gbayi lawujo ti won ko sii fe ni SUURU lati sise Kara Kara fun.Gbogbo èyi lo si tin daa ri won lati maa gbe Igbe aye tii ko bo ju mu.

Pupo ninu won lo tii lo ko ese ara won si inu orisirisi iwa ati ise buruku ti o lodi sii Ona Olorun, tii won yoosi Wa kaa bamo leyin waa Ola. Ko sii idi kan Rara lati kanju gbè ilè ayè Ofofo. O daa lati fi SUURU sè oun kooun tii a baa n sè. SUURU ni kookoro oun gbogbo ati aseyori. SUURU ni a fin baa ara wa gbè laarin ara Wa. SUURU a maa fun ni la Laafia.

Surulere!

#StayCrowned⚜️

Written by 

Related posts

One thought on “Surulere!

  1. Omolola Iyanu-Oluwa

    Awesome!

Leave a Comment

Thank you for dropping a comment. You are so crowned!

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.